Hello everyone!
My name is Miss Adeola Oguntuga T, and I’m a passionate Yoruba language tutor dedicated to helping learners of all levels speak, read, and understand Yoruba with confidence.
Ẹ káàbọ o!
Orúkọ mi ni Omidan Adeola Oguntuga , mo sì jẹ olùkọ èdè Yorùbá tó nífẹẹ púpọ sí kíkọ èdè àti àṣà Yorùbá.
Mo ní ìrírí nípa kíkọ Yorùbá fún àwọn akẹkọọ tó jẹ alakọbẹrẹ àti àwọn tó fẹ túbọ mọ èdè naa síi. Ìdí mi ni láti jẹ kí ẹkọ Yorùbá rọrùn, dùn, àti ní ìtàn àṣà tó jinlẹ.
Tó bá ti jẹ pé o fẹ máa sọ Yorùbá dáadáa àti mọ ìtàn àṣà wa, ẹ wà ní ibi tó tọ!
Ẹ jẹ ká kọ Yorùbá papọ!