tre.gif
Sell faster
Buy smarter
  1. All ads
  2. Sports, Arts & Outdoors
  3. Books & Games
Lagos, Ikeja
3 views

Burdah Arabic Yoruba Translation

+1
Brand New
Condition
Books
Type
Religion
Genre
100
Number of Pages
2021
Publication Year
Paperback
Format
Delivery
Lagos State • Lagos Island (Eko)
1 day
Free of charge
Store address
Lagos State • Lagos Island (Eko)
89,Randle Avenue
Open now
• Mon - Sun, 07:00-20:00
Qasidatu al Burdah je orin ti Alfa Muhammad Omo Sahid Omo hamma'd Omo Abdullah, Ara Masari lati iran Ni won sinsi oko orin yi lati fi yin Anabi Muhammad ti o si fi ogo ati ola nla ti owa fun Anabi han ki ike ati ola ki oma baa. Awon ipin orin yin je mewa: Ori kinni oso nipa ife ati ijeran ti oluko tira naa ni si ojise nla Anabi Muhammad salalahu alachi wasalam. Ori keji ni orin nipa ife inu ati erongba. Ori keta ni oro nipa eyin fun Ojise Olohun (S.A.W) Ori kerin lo so nipa bibi Ojise Olohun (S.A.W)) Ori karun lo so nipa Ibukun ati Anu Olohun lori ojise Olohun (S.A.W) ti ofi ran nise.Ori kefa lo so nipa iyi to nbe fun Al-Kurian.Ori keje naa so nipa Gigun san mo Onise nla Olohun, ki ike ati ige Olohun maa ba Ori kejo ohun ni oro nipa (Al-jihad) Ijagun si oju ona Olohun ti Anabi Muhammad ja.
1,000

₦ 500

≥ 50 pieces
Safety tips
  • Avoid paying in advance, even for delivery
  • Meet with the seller at a safe public place
  • Inspect the item and ensure it's exactly what you want
  • Make sure that the packed item is the one you've inspected
  • Only pay if you're satisfied